A kí bàbá wa Tayelolu Hassan A.K.A Ògògó ọmọ kulodo kú ayẹyẹ ọjọ́ ìbí wọn tí ó ko lónìí. Ẹ ma pé fún wa nínú ayọ̀, àlàáfíà. @alhajitaiwo #OgogoOmoKulodo #OjoIbi #TaiwoHassan #EdeYorubaRewa (at Birmingham, United Kingdom) https://www.instagram.com/p/B4SokGMJN0v/?igshid=u6idfzqimwdt










