Ohun míràn tí mo tún ṣe alabapade nínú yàrá ìwé mi (my Library). Mo féràn ìwé yìí púpọ̀... Abala wo ni ẹyin féràn jù inú ìwé yìí.? #EegunAlare #YorubaDunKa #EdeYorubaRewa #OmoYorubaNiMi (at Sheldon Country Park) https://www.instagram.com/p/B4AND5fJcHy/?igshid=1qsgkkfeecglv











