Oruko mi ni, TIJANI SHERIFDEEN AKINOLA Mo je omo Bibi ilu IBADAN. Ise ti mo yan layo ni ki aran aso, ki afi aworan si iwaju e, Tabi ki a ko eyikeyi nkan ti oba wunwa siwaju e. inumi Madun ti ebale fun mi Ni owo yi, ale mu idagba soke ba ise mi, yosi le je kin ra irinse kun eyi ti moti ni tele, Yosi fun mi ni anfani lati le ko awon odo biwon se se ise Yi. Yala si igba ti afin fi oda se aso. ESE GAN. #ISEDOWO2018 @goldberg_ng @XD_PROMPT_APPAREL (at The polytechnic, ibadan. oyo state, Nigeria. poly road sango ibadan, 2011-2014)












