Apeta: Artefact, the rising
Itan pada s’ile.
Awọn Yoruba, wá́ dupẹ lori ipada awọn Apẹta ti wọn ji nigbati n gbati.
Tinu,Oniwa Agba n ṣiṣẹ lati gbe wọn pada.
Lojiji, laisọ nkan kan. Iṣẹ Ipada wa duro. Ì̀wọsi lori ipalara, wọn gbe gbogbo apẹta pọ, wọn wá́ tun ta lẹẹnkansi. Wọn tun ka si gbogbo. Ilú́ rò̀ pe ko si nkan ṣe mọ. Ṣugbọn Olurá wá pe Tinu.́ O lọ wo Iboju Egungun. O wa ri aṣiri nla, Olura ọkunrin wá ku danu. Tinu kọ iṣẹ Archeology, ṣugbọn o ni agbara oju.
Pẹlu ẹbun o le ri nkan ninu.
O ri pe okù̀n dipọ gbogbo enikẹni ọkunrin to din, to ra gbogbo Apẹta. Ọna kan lo wa lati da duro iku. O ni lati wa, ati da Apẹta si ile wọn pada. Njẹ Tinu le ri Apẹta,wa da wọn pada kia-kia?
History returned.
The Yorubas were celebrating the return of their Artefacts of old that were looted. Tinu, an Archeologist works to bring them home.
But suddenly, with no word the return is stopped. With further insult, they are gathered together and sold off again. The Artefacts are again scattered.They thought all was lost but one of the buyers calls Tinu to examine his Egungun Mask. She discovers a secret before the male buyer dies.
Tinu is trained in Archeology but is gifted with the sight.
She sees there is a thread tying together all the men who bought and sold the relics.
The only way to stop these deaths. She has to find and return the relics to their homes.
Can Tinu find and return them in time?
L'histoire est revenue.
Les Yorubas célébraient le retour de leurs artefacts de vieux qui ont été pillés. Tinu, une femme archéologue travaille à retournée des reliques a leurs pais d’origin.
Mais soudainement, sans mot, le retour est arrêté. Avec d'autres insultes, elles sont rassemblées et vendues à nouveau. Les artefacts sont à nouveau dispersés. Ils pensaient que tout était perdu, mais l'un des acheteurs appelle Tinu pour examiner son masque Egungun. Elle découvre un secret avant que l'acheteur masculin meurt.
Tinu est formé à l'archéologie mais est doué de la vue.
Elle voit qu'il y a un fil qui attache tous les hommes qui ont acheté et vendu les reliques.
Le seul moyen d'arrêter ces décès. Elle doit trouver et retourner les reliques à leurs maisons.
Est-ce que la femme, Tinu peut trouver et les retourner dans le temps?
La historia regresó.
Los Yorubas celebraban el regreso de sus artefactos de antaño que fueron saqueados. Tinu, una arqueóloga trabaja para traerlos de vuelta a su país de origen.
Pero de repente, sin ninguna palabra el retorno se detiene. Con más insulto, se reúnen y se venden de nuevo. Los artefactos son de nuevo dispersos. Se pensó que todo estaba perdido, pero uno de los compradores llama a Tinu para examinar su máscara de Egungun. Ella descubre un secreto antes de que muere el comprador masculino.
Tinu está entrenado en arqueología, pero está dotado con la vista.
Ella ve que hay un hilo atado a todos los hombres que compraron y vendieron las reliquias.
La única forma de detener estas muertes. Ella tiene que encontrar y devolver las reliquias a sus hogares.
¿Puede Tinu encontrar y devolverlos a tiempo?















